Jeremáyà 1:16 BMY

16 Èmi yóò sì kéde ìdájọ́ mi lóríàwọn ènìyàn mi nítorí ìwàbúburú wọn nípa kíkọ̀ mísílẹ̀, nípa rírúbọ sí Ọlọ́runmìíràn àti sínsin àwọn ohuntí wọ́n fi ọwọ́ wọn ṣe.

Ka pipe ipin Jeremáyà 1

Wo Jeremáyà 1:16 ni o tọ