Jeremáyà 1:17 BMY

17 “Wà ní ìmúrasílẹ̀! Dìde dúró kí o sì sọ fún wọn ohunkóhun tí mo bá pa lásẹ fún wọn. Má ṣe jẹ́ kí wọn dẹ́rù bà ọ́, èmi yóò sì sọ ọ́ di ẹ̀rù níwájú wọn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 1

Wo Jeremáyà 1:17 ni o tọ