Jeremáyà 1:18 BMY

18 Ní òní èmi ti sọ ọ́ di orílẹ̀ èdè alágbára, òpó ìrin àti odi idẹ sí àwọn Ọba Júdà, àwọn ìjòyè rẹ̀, sí àwọn àlùfáà àti àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 1

Wo Jeremáyà 1:18 ni o tọ