Jeremáyà 1:19 BMY

19 Wọn yóò dojú ìjà kọọ́, wọn kì yóò borí rẹ, nítorí wí pé èmi wà pẹ̀lú rẹ, èmi yóò sì gbà ọ́,” ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 1

Wo Jeremáyà 1:19 ni o tọ