Jeremáyà 11:11 BMY

11 Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa wí: ‘Èmi yóò mu ibi tí wọn kò ní le è yẹ̀ wá sorí wọn, bí wọ́n tilẹ̀ ké pè mí èmi kì yóò fetí sí igbe wọn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 11

Wo Jeremáyà 11:11 ni o tọ