Jeremáyà 11:12 BMY

12 Àwọn ìlú Júdà àti àwọn ará Jérúsálẹ́mù yóò lọ kégbe sí àwọn òrìṣà tí wọ́n ń sun tùràrí sí; àwọn òrìṣà náà kò ní ràn wọ́n lọ́wọ́ ní ìgbà tí ìpọ́nju òhún bá dé.

Ka pipe ipin Jeremáyà 11

Wo Jeremáyà 11:12 ni o tọ