Jeremáyà 11:5 BMY

5 Nígbà náà ni Èmi ó sì mú ìlérí tí mo búra fún àwọn baba ńlá yín ṣẹ; láti fún wọn ní ilẹ̀ tí ó ń ṣàn fún wàrà àti fún oyin,’ ilẹ̀ tí ẹ ní lónìí.”Mo sì dáhùn wí pé, “Àmí, Olúwa.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 11

Wo Jeremáyà 11:5 ni o tọ