Jeremáyà 11:6 BMY

6 Olúwa wí fún mi pé, “Kéde gbogbo ọ̀rọ̀ yìí ní àwọn ìlú Júdà àti ní ìgboro Jérúsálẹ́mù pé, ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ ìlérí yìí, kí ẹ sì máa tẹ̀lé wọn.

Ka pipe ipin Jeremáyà 11

Wo Jeremáyà 11:6 ni o tọ