Jeremáyà 11:7 BMY

7 Láti ìgbà tí mo ti mú àwọn baba yín jáde láti ilẹ̀ Éjíbítì wá títí di òní, mo kìlọ̀ fún wọn lọ́pọ̀ ìgbà wí pé, “Ẹ gbọ́ tèmi.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 11

Wo Jeremáyà 11:7 ni o tọ