Jeremáyà 12:10 BMY

10 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùṣọ́ àgùntàn ni yóò sì ba oko àjàrà mi jẹ́,tí wọn yóò sì tẹ oko mi mọ́lẹ̀;Wọ́n ó sọ oko dídára mi diibi tí a ń da ìdọ̀tí sí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 12

Wo Jeremáyà 12:10 ni o tọ