Jeremáyà 13:18 BMY

18 Sọ fún Ọba àti ayaba pé,“Ẹ rẹ ara yín sílẹ̀,ẹ sọ̀kalẹ̀ láti orí ìtẹ́ yín,adé ògo yín bọ́ sí ilẹ̀ láti orí yín.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 13

Wo Jeremáyà 13:18 ni o tọ