Jeremáyà 13:19 BMY

19 Àwọn orílẹ̀ èdè tí ó wà ní Négéfì ni à ó tì pa,kò sì ní sí ẹnikẹ́ni láti sí wọn.Gbogbo Júdà ni a ó kó lọ sí ilẹ̀ ìgbèkùn,gbogbo wọn ni a ó kó lọ pátapáta.

Ka pipe ipin Jeremáyà 13

Wo Jeremáyà 13:19 ni o tọ