11 Ṣùgbọ́n Olúwa wà pẹ̀lú mi gẹ́gẹ́ bí jagunjagun alágbára.Nítorí náà, àwọn tí ó ń lépa mi yóò kọsẹ̀,wọn kì yóò sì borí.Wọn yóò kùnà, wọn yóò sì gba ìtìjú púpọ̀.Àbùkù wọn kì yóò sì di ohun ìgbàgbé.
Ka pipe ipin Jeremáyà 20
Wo Jeremáyà 20:11 ni o tọ