Jeremáyà 20:12 BMY

12 Olúwa alágbára, ìwọ tí ó ń dán olódodo pípé wòtí o sì ń ṣe àyẹ̀wò ọkàn àti ẹ̀yà fínní-fínní,jẹ́ kí èmi kí ó rí ìgbẹ̀san rẹ lórí wọn,nítorí ìwọ ni mo gbé ara mi lé.

Ka pipe ipin Jeremáyà 20

Wo Jeremáyà 20:12 ni o tọ