Jeremáyà 30:17 BMY

17 Ṣùgbọ́n èmi yóò fi ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìlera fún yín,n ó sì wo ọ̀gbẹ́ yín sàn,’ni Olúwa wí,‘nítorí tí a pè yín ní alárìnkiriSíónì tí gbogbo ènìyàn dágunlá sí.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 30

Wo Jeremáyà 30:17 ni o tọ