Jeremáyà 30:18 BMY

18 “Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“ ‘Èmi yóò dá gbogbo ire àgọ́ Jákọ́bù padà,èmi yóò sì ṣe àánú fún olùgbé àgọ́ rẹ̀;ìlú náà yóò sì di títúnṣetí ààfin ìlú náà yóò sì wà ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 30

Wo Jeremáyà 30:18 ni o tọ