Jeremáyà 30:19 BMY

19 Láti ẹnu wọn ni orin ọpẹ́ àtiìyìn yóò sì ti máa jáde.Èmi yóò sọ wọ́n di púpọ̀,wọn kì yóò sì dínkù ní iye,Èmi yóò fi ọlá fún wọn,wọn kò sì ní di ẹni àbùkù.

Ka pipe ipin Jeremáyà 30

Wo Jeremáyà 30:19 ni o tọ