Jeremáyà 31:27 BMY

27 “Wò ó, ọjọ́ ń bọ̀,” ni Olúwa wí, “nígbà tí èmi yóò gbin ilé Ísírẹ́lì àti ilé Júdà pẹ̀lú irúgbìn ọmọ ènìyàn àti ẹranko.

Ka pipe ipin Jeremáyà 31

Wo Jeremáyà 31:27 ni o tọ