Jeremáyà 33:11 BMY

11 Ariwo di ayọ̀ àti inú dídùn, ohùn ìyàwó àti ti ọkọ ìyàwó àti ohùn àwọn tí ó ru ẹbọ ọpẹ́ wọn nílé Olúwa wí pé:“Yin Olúwa àwọn ọmọ ogun,nítorí Olúwa dára,ìfẹ́ rẹ̀ dúró títí láéláé.”Nítorí èmi ó dá ìkólọ ilẹ̀ náà padà sí bí o ṣe wà tẹ́lẹ̀ ni Olúwa wí:

Ka pipe ipin Jeremáyà 33

Wo Jeremáyà 33:11 ni o tọ