Jeremáyà 33:12 BMY

12 “Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ ogun wí, ‘Ní ilẹ̀ yìí tí ó ti dahoro láìsí ọkùnrin àti àwọn ẹran nínú gbogbo ìlú, kò ní sí pápá oko fún àwọn olùṣọ́ àgùntàn láti mú àwọn ẹran ọ̀sìn wọn sinmi.

Ka pipe ipin Jeremáyà 33

Wo Jeremáyà 33:12 ni o tọ