Jeremáyà 33:14 BMY

14 “ ‘Àwọn ọjọ́ náà ń bọ̀,’ ni Olúwa wí, ‘tí èmi ó mú ìlérí rere tí mo ṣe fún ilé Ísírẹ́lì àti ilé Júdà ṣẹ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 33

Wo Jeremáyà 33:14 ni o tọ