Jeremáyà 33:15 BMY

15 “ ‘Ní ọjọ́ wọ̀n ọn nì àti ní àkókò náà,Èmi ó gbé olódodo dìde láti ẹ̀ka Dáfídì.Yóò ṣe ìdájọ́ àti ohun tí ó tọ́ ní ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 33

Wo Jeremáyà 33:15 ni o tọ