Jeremáyà 4:19 BMY

19 Áà! Ìrora mi, ìrora mi!Mo yí nínú ìrora.Áà!, ìrora ọkàn mi!Ọkàn mi lù kìkì nínú mi,N kò le è dákẹ́.Nítorí mo ti gbọ́ ohùn ìpè,Mo sì ti gbọ́ igbe ogun.

Ka pipe ipin Jeremáyà 4

Wo Jeremáyà 4:19 ni o tọ