Jeremáyà 4:20 BMY

20 Ìparun ń gorí ìparun;Gbogbo ilẹ̀ náà sì ṣubú sínú ìparunLọ́gán a wó àwọn àgọ́ mi,tí ó jẹ́ ohun ààbò mi níṣẹ́jú kan.

Ka pipe ipin Jeremáyà 4

Wo Jeremáyà 4:20 ni o tọ