Jeremáyà 4:5 BMY

5 “Kéde ní Júdà, kí o sì polongo ní Jérúsálẹ́mù, kí o sì wí pé:‘fun fèrè káàkiri gbogbo ilẹ̀. Kí o sì kígbe,‘kó ara jọ pọ̀!Jẹ́ kí a sálọ sí ìlú olódi.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 4

Wo Jeremáyà 4:5 ni o tọ