Jeremáyà 4:6 BMY

6 Fi àmì láti sálọ sí Síónì hàn,sálọ fún ààbò láìsí ìdádúró.Nítorí èmi ó mú àjálù láti àríwá wá,àní ìparun tí ó burú jọjọ.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 4

Wo Jeremáyà 4:6 ni o tọ