Jeremáyà 40:1 BMY

1 Ọ̀rọ̀ náà sì tọ Jeremáyà wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa lẹ́yìn tí Nebukadinésárì balógun àwọn ẹ̀ṣọ́ ti tú u sílẹ̀ ní Rámà. Ó rí Jeremáyà tí a fi ẹ̀wọ̀n dè láàrin gbogbo àwọn tí wọ́n mú ní Jérúsálẹ́mù àti Júdà. Wọ́n kó lọ sí ilẹ̀ àjèjì Bábílónì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 40

Wo Jeremáyà 40:1 ni o tọ