Jeremáyà 41:13 BMY

13 Nígbà tí gbogbo àwọn ènìyàn Ísímáẹ́lì tí wọ́n wà pẹ̀lú rẹ̀ rí Jóhánánì ọmọkùnrin Káréà àti àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n sì yọ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 41

Wo Jeremáyà 41:13 ni o tọ