Jeremáyà 41:14 BMY

14 Gbogbo àwọn ènìyàn tí Ísímáẹ́lì ti kó ní ìgbékùn ní Mísípà yípadà, wọ́n sì lọ sọ́dọ̀ Jóhánánì ọmọ Káréà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 41

Wo Jeremáyà 41:14 ni o tọ