Jeremáyà 41:15 BMY

15 Ṣùgbọ́n Ísímáẹ́lì ọmọkùnrin Nétanáyà àti àwọn mẹ́jọ nínú àwọn ọkùnrin rẹ̀ bọ́ lọ́wọ́ Jóhánánì, wọ́n sì sálọ sí Ámónì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 41

Wo Jeremáyà 41:15 ni o tọ