Jeremáyà 44:27 BMY

27 Nítorí náà, mò ń wò wọ́n bí i fún ìparun, kì í ṣe fún rere. Àwọn Júù tí ó wà ní Éjíbítì yóò parun pẹ̀lú idà àti ìyàn títí tí gbogbo wọn yóò fi parun.

Ka pipe ipin Jeremáyà 44

Wo Jeremáyà 44:27 ni o tọ