Jeremáyà 44:4 BMY

4 Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ní mo rán wòlíì mi, èyí tí ó wí báyìí pé, ‘Má ṣe àwọn ohun búburú tí èmi kò fẹ́.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 44

Wo Jeremáyà 44:4 ni o tọ