Jeremáyà 5:1 BMY

1 “Lọ sókè àti sódò àwọn òpó Jérúsálẹ́mùWò yíká, kí o sì mọ̀,kí o sì wá kiriBí o bá le è rí ẹnìkan,tí ó jẹ́ olóòótọ́ àti olódodo,N ó dárí jìn ìlú yìí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 5

Wo Jeremáyà 5:1 ni o tọ