Jeremáyà 52:10 BMY

10 Ní Ríbílà ni Ọba Bábílónì ti pa ọmọkùnrin Sedekáyà lójú rẹ̀; ó sì tún pa gbogbo àwọn aláṣẹ Júdà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 52

Wo Jeremáyà 52:10 ni o tọ