Jeremáyà 52:11 BMY

11 Lẹ́yìn náà, o yọ ojú Ṣedekáyà síta, o sì fi ẹ̀wọ̀n yìí dì í, ó sì gbe e lọ sí Bábílónì níbi tí ó ti fi sínú ọ̀gbà ẹ̀wọ̀n títí di ikú ọjọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 52

Wo Jeremáyà 52:11 ni o tọ