Jeremáyà 52:17 BMY

17 Àwọn Bábílónì fọ́ idẹ ìpìlẹ̀ àti àwọn ìjókòó tó ṣe é gbé kúrò àti àwọn ìdè wọ̀n-ọn-nì tí ń bẹ ní pẹpẹ Olúwa. Wọ́n sì kó gbogbo idẹ náà lọ sí Bábílónì.

Ka pipe ipin Jeremáyà 52

Wo Jeremáyà 52:17 ni o tọ