Jeremáyà 52:18 BMY

18 Bákan náà, wọ́n tún kó àwọn ìkòkò, ọkọ́ àti ọ̀pá fìtílà, àwọn ọpọ́n, síbí àti gbogbo ohun èlò idẹ tí wọ́n ń lò níbi pẹpẹ lọ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 52

Wo Jeremáyà 52:18 ni o tọ