Jeremáyà 8:6 BMY

6 Mo ti fetí sílẹ̀ dáradára, wọnkò sọ ohun tí ó tọ́. Kò sí ẹnìkan tóronúpìwàdà nínú ìwà búburú rẹ̀,kí ó wí pé, “Kí ni mo ṣe?” Olúkúlùkùń tọ ọ̀nà rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹṣin tó ń lọ sójú ogun.

Ka pipe ipin Jeremáyà 8

Wo Jeremáyà 8:6 ni o tọ