Esek 11:22 YCE

22 Awọn kerubu si gbe iyẹ́ wọn soke, pelu awọn kẹkẹ́ lẹgbẹ wọn, ogo Ọlọrun Israeli si wà lori wọn loke.

Ka pipe ipin Esek 11

Wo Esek 11:22 ni o tọ