Esek 2:4 YCE

4 Nitori ọmọ alafojudi ati ọlọkàn lile ni nwọn, Emi rán ọ si wọn; iwọ o si wi fun wọn pe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi.

Ka pipe ipin Esek 2

Wo Esek 2:4 ni o tọ