Esek 20:30 YCE

30 Si wi fun ile Israeli pe, Bayi ni Oluwa Ọlọrun wi; A bà nyin jẹ́ gẹgẹ bi baba nyin? ẹnyin si ṣe agbère gẹgẹ bi ohun-irira wọn?

Ka pipe ipin Esek 20

Wo Esek 20:30 ni o tọ