Esek 20:43 YCE

43 Nibẹ li ẹnyin o ranti ọ̀na nyin, ati gbogbo iṣe nyin, ninu eyiti a ti bà nyin jẹ; ẹ o si sú ara nyin loju ara nyin nitori gbogbo buburu ti ẹnyin ti ṣe.

Ka pipe ipin Esek 20

Wo Esek 20:43 ni o tọ