Esek 22:7 YCE

7 Ninu rẹ ni nwọn kò ka baba ati iyá si: lãrin rẹ ni nwọn ti ni awọn alejo lara: ninu rẹ ni nwọn ti bà alaini-baba ati opo ninu jẹ.

Ka pipe ipin Esek 22

Wo Esek 22:7 ni o tọ