Esek 23:47 YCE

47 Ẹgbẹ na yio si sọ wọn li okuta, nwọn o si fi idà pa wọn; nwọn o pa awọn ọmọ wọn ọkunrin, ati awọn ọmọ wọn obinrin, nwọn o si fi iná kun ile wọn.

Ka pipe ipin Esek 23

Wo Esek 23:47 ni o tọ