Esek 25:10 YCE

10 Fun awọn ọmọ ìla-orun, pẹlu awọn ara Ammoni, emi o si fi wọn fun ni ni iní; ki a má ba ranti awọn ara Ammoni lãrin orilẹ-ède mọ.

Ka pipe ipin Esek 25

Wo Esek 25:10 ni o tọ