Esek 26:14 YCE

14 Emi o si ṣe ọ bi ori apáta; iwọ o si jẹ ibi lati nà awọ̀n le lori; a kì yio kọ́ ọ mọ: nitori emi Oluwa li o ti sọ ọ, li Oluwa Ọlọrun wi.

Ka pipe ipin Esek 26

Wo Esek 26:14 ni o tọ