Esek 28:19 YCE

19 Gbogbo awọn ti o mọ̀ ọ lãrin awọn orilẹ-ède li ẹnu o yà si ọ: iwọ o jẹ ẹ̀ru, iwọ kì yio si si mọ́ lailai.

Ka pipe ipin Esek 28

Wo Esek 28:19 ni o tọ