Esek 29:21 YCE

21 Li ọjọ na li emi o mu ki iwọ Israeli rú jade, emi o si fun ọ ni iṣínu li ãrin wọn; nwọn o si mọ̀ pe emi li Oluwa.

Ka pipe ipin Esek 29

Wo Esek 29:21 ni o tọ