Esek 3:13 YCE

13 Mo si gbọ́ ariwo iyẹ́ awọn ẹ̀da alãye, ti o kàn ara wọn, ati ariwo awọn kẹkẹ́ ti o wà pẹlu wọn, ati ariwo iró nla.

Ka pipe ipin Esek 3

Wo Esek 3:13 ni o tọ