Esek 3:21 YCE

21 Ṣugbọn bi iwọ ba kilọ fun olododo, ki olododo ki o má dẹ̀ṣẹ, ti on kò si ṣẹ̀, yio yè nitotọ, nitori ti a kilọ fun u, ọrùn rẹ si mọ́.

Ka pipe ipin Esek 3

Wo Esek 3:21 ni o tọ